Jump to content

Serzh Sargsyan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
The printable version is no longer supported and may have rendering errors. Please update your browser bookmarks and please use the default browser print function instead.
Serzh Sargsyan
Սերժ Սարգսյան
Aare ile Armenia
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
9 April 2008
Alákóso ÀgbàTigran Sargsyan
AsíwájúRobert Kocharyan
Alakoso Agba ile Armenia
In office
26 March 2007 – 9 April 2008
ÀàrẹRobert Kocharyan
AsíwájúAndranik Margaryan
Arọ́pòTigran Sargsyan
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí30 Oṣù Kẹfà 1954 (1954-06-30) (ọmọ ọdún 70)
Stepanakert, Nagorno-Karabakh AO Azerbaijan SSR, Soviet Union (now Stepankert, Nagorno-Karabakh Republic)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúRepublican Party
(Àwọn) olólùfẹ́Rita Sargsyan
Alma materYerevan State University

Serzh Azati Sargsyan (Arméníà: Սերժ Ազատի Սարգսյան, ojoibi June 30, 1954[1]) ni Aare orile-ede Armenia. O bori ninu idiboya Aare Osu Keji 2008[2] o si bo si ori aga ni Osu Kerin 2008.[3] Ko ni ibatan mo Tigran Sargsyan to je Alakoso Agba ile Armenia lowo.



Itokasi

  1. "Official biography of Serzh Sargsyan". Archived from the original on 2010-12-19. Retrieved 2010-08-08. 
  2. "RPA nominates Serge Sargsyan for President". PanArmenian.net. 2007-11-10. http://www.panarmenian.net/news/eng/?nid=24036. Retrieved 2007-11-11. 
  3. "Armenia: Sarkisian Sworn In As President" Archived 2008-04-22 at the Wayback Machine., Radio Free Europe/Radio Liberty, April 9, 2008.