Ṣẹ́gun Toríọlá
Appearance
![](http://178.128.105.246/cars-http-upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/8/89/Segun_Toriola_2012_%28cropped%29.jpg/220px-Segun_Toriola_2012_%28cropped%29.jpg)
Ṣẹ́gun Moses Toríọlá tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kejìdínlógún Oṣù kẹsàn-án ọdún 1974 (18th September 1974) jẹ́ gbajúgbajà eléré ìdárayá ẹyin orí àga (Table Tennis) ọmọ bíbí ìlú Ìlọrin, ní ìpínlẹ̀ Kwara, lórílẹ̀ èdè Nigeria).[1]
Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
- ↑ "ITTF_Database". Ittf.com. Archived from the original on 17 October 2012. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)